Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ǹjẹ́ o rò pé ìdílé lè jẹ́ aláyọ̀ lásìkò tí nǹkan nira yìí tí ọ̀pọ̀ ìṣòro sì dojú kọ àwọn tọkọtaya àti ìdílé? Ọ̀rọ̀ yìí kò rọrùn rárá o. Ṣùgbọ́n ọ̀nà àbáyọ wà. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe gbogbo ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ ìdílé ló wà nínú ìwé yìí, ó sọ àwọn ìlànà pàtàkì látinú Bíbélì àti àwọn ìmọ̀ràn tó wúlò gan-an. Tí o bá fi wọ́n sílò bó ṣe yẹ, ó máa jẹ́ kí ìdílé rẹ ní ayọ̀.