Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé? (Apá 2)

Orí kọkànlá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Gbé àwọn ìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gba ìjìyà yẹ̀ wò àti bí ohun tó ṣe yẹn ṣe fi hàn pé ó jẹ́ ọlọ́gbọ́n.