Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Czech Republic

Ìsọfúnni Ṣókí—Czech Republic

  • 10,851,000—Iye àwọn èèyàn
  • 16,764—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 217—Iye àwọn ìjọ
  • 657—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Àwọn Ilé Ẹjọ́ ní Czech Republic àti Slovakia Dá Àwọn Ará Wa Láre

Láti May 1, 2017 sí January 8, 2018, àwọn ilé ẹjọ́ dá àwọn ará wa láre lẹ́yìn tí ilé ẹjọ́ ti fẹ̀sùn ọ̀daràn kàn wọ́n lọ́pọ̀ ọdún sẹ́yìn torí pé ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun tàbí pé wọ́n ń ṣiṣẹ́ ìwàásù.