Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Thailand

  • Damnoen Saduak, Thailand—Wọ́n ń wàásù nínú ọjà orí omi

Ìsọfúnni Ṣókí—Thailand

  • 70,183,000—Iye àwọn èèyàn
  • 5,350—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 144—Iye àwọn ìjọ
  • 13,275—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Ilé Iṣẹ́ Ìjọba Thailand “Gbóríyìn àti Òṣùbà” Fáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Nílẹ̀ Peru Torí Wọ́n Ṣèrànwọ́ Fáwọn Ọmọ Ilẹ̀ Thailand Tó Wà Lẹ́wọ̀n

Àwọn aṣojú Ilé Iṣẹ́ Ìjọba Thailand wá sọ́dọ̀ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Peru láti dúpẹ́ lọ́wọ́ wọn fún ohun tí wọ́n ṣe àti bí wọ́n ṣe ṣèrànwọ́ fáwọn ọmọ ilẹ̀ Thailand tó wà lẹ́wọ̀n.

ÌRÒYÌN

Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Thailand Ń Fi Ìwé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ran Àwọn Aráàlú Lọ́wọ́ Kí Ìlú Lè Dàgbà Sókè

Àtọdún mẹ́ta sẹ́yìn ni àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Thailand ti ń lo ìwé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà láti ran àwọn aráàlú lọ́wọ́.