Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Venezuela

  • La Victoria, Venezuela​—Wọ́n ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́

Ìsọfúnni Ṣókí—Venezuela

  • 28,302,000—Iye àwọn èèyàn
  • 134,096—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,700—Iye àwọn ìjọ
  • 215—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÍRÍ

Wọ́n Ń Sin Jèhófà Láìka Bí Nǹkan Ṣe Le Tó Lórílẹ̀-Èdè Fẹnẹsúélà

Àwọn ará wa lórílẹ̀-èdè Fẹnẹsúélà ń fìtara wàásù, wọ́n sì jẹ́ “orísun ìtùnú” fún ara wọn.

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

Bá A Ṣe Pèsè Ìrànwọ́ Lọ́dún 2021—A Ò Pa Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Wa Tì

Lọ́dún 2021, a ṣèrànwọ́ fáwọn ará wa láwọn orílẹ̀-èdè kan tí àrùn Corona àtàwọn àjálù míì ti fojú wọn rí màbo.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Mo Máa Ń Ro Ti Jèhófà Tí Mo Bá Ń Ṣèpinnu

Ìtàn ìgbésí ayé: Dyah Yazbek

ÌRÒYÌN

Ìròyìn Láti Fẹnẹsúélà: Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Túbọ̀ Tẹra Mọ́ Ìjọsìn Ọlọ́run Láìka Ìṣòro Sí

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé nǹkan nira gan-an, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Fẹnẹsúélà ò yéé fìgboyà wàásù.