Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ayé yìí ti dojú rú. Bó pẹ́ bó yá, àjálù àtàwọn ìṣòro míì táwọn èèyàn fọwọ́ ara wọn fà lè mú kí nǹkan nira fún wa lẹ́nì kọ̀ọ̀kan. Kí ló lè ran ìwọ àti ìdílé ẹ lọ́wọ́ kí ọkàn yín lè balẹ̀ bẹ́ ẹ tiẹ̀ ń kojú àwọn ìṣòro tó wà láyé yìí?

1 | Tọ́jú Ara Rẹ

2 | Ṣe Ohun Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Àtijẹ Àtimu Nira Fún Ẹ

3 | Jẹ́ Kí Àjọṣe Ìwọ àti Tẹbítọ̀rẹ́ Dáa Sí I

4 | Gbà Pé Ọ̀la Ń Bọ̀ Wá Dáa