Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé

Àwọn Ọ̀rẹ́

Kí Nìdí Tí Mi Ò Fi Ní Ọ̀rẹ́ Kankan?

Kì í ṣe ìwọ nìkan ló máa ń ṣe bíi pé ó dá wà tàbí pé kò ní ọ̀rẹ́. Kà nípa bí àwọn ẹgbẹ́ rẹ ṣe borí èrò yìí.

Kí Ni Mo lè Ṣe Tí Mi Ò Fi Ní Máa Tijú Mọ́?

Máa wá bó o ṣe lè ní àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́, kó o lè mọ àwọn ohun tó ò mọ̀ tẹ́lẹ̀.

Ṣó Yẹ Kí N Mú Àwọn Míì Lọ́rẹ̀ẹ́ Yàtọ̀ Sáwọn Tá A Ti Jọ Ń Ṣọ̀rẹ́?

Tó o bá wà láàárín àwọn pàtó kan tẹ́ ẹ ti jọ ń ṣọ̀rẹ́, ó lè mára tù ẹ́, àmọ́ kì í fìgbà gbogbo ṣàǹfààní. Kí nìdí?

Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán Ni Wá àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́?—Apá 2: Báwo Ní Mo Ṣe Ń Ṣe sí Ẹni Yìí?

Ṣé kì í ṣe pé ọ̀rẹ́ rẹ ti ń wò ó pé o fẹ́ kí ẹ máa fẹ́ra? Wo àwọn àbá yìí.

Kí Ni Kí Ń Ṣe Tí Ọ̀rẹ́ Mi Bá Ṣe Nǹkan Tó Dùn Mí?

Arẹ́májà kan ò sí. Ṣùgbọ́n kí lo lè ṣe tí ọ̀rẹ́ rẹ bá ṣe ohun tó dùn ẹ́?

Kí Nìdí Táwọn Ẹgbẹ́ Mi Ò Fi Gba Tèmi?

Èwo ló dáa jù nínú káwọn tíwà wọn ò dáa gba tìẹ àti pé kó o jẹ́ káwọn èèyàn mọ irú ẹni tó o jẹ́ gan an?

Kí Ló Dé Tó Jẹ́ Ọ̀rọ̀ Tí Ò Dáa Ló Máa Ń Jáde Lẹ́nu Mi Ṣáá?

Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí wàá fi máa ronú kó o tó sọ̀rọ̀?

Ṣé Ó Burú Kéèyàn Máa Tage?

Kí ló túmọ̀ sí gan-an kéèyàn máa tage? Kí ló máa ń mú káwọn kan ṣe bẹ́ẹ̀? Ṣé ó tiẹ̀ léwu?

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?

Ọ̀rọ tó o fi ránṣẹ́ lórí fóònù lè ba àjọṣe tó o ní pẹ̀lú àwọn míì jẹ́, ó sì lè bà ẹ́ lórúkọ̀ jẹ́. Kà bó ṣe lè ṣẹlẹ̀.

Ìdílé

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Lóye Àwọn Òbí Mi?

Wo ọ̀nà márùn-ún tó o lè gbà yẹra fún aáwọ̀ kó o sì dín ohun tó ń fa aáwọ̀ kù.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀ Nípa Àwọn Òfin Tí Wọ́n Ṣe?

Kọ́ bó o ṣe lè bá àwọn òbí ẹ sọ̀rọ̀ tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀, ohun rere tó máa tibẹ̀ yọ lè yà ẹ́ lẹ́nu.

Ṣé Dandan Ni Kí Wọ́n Ṣe Òfin Nínú Ilé?

Ṣé òfin táwọn òbí ẹ ṣe nínú ilé ò bá ẹ lára mu? Àwọn ìmọ̀ràn kan nìyí tó máa jẹ́ kó o máa fi ojú tó tọ́ wò ó.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Mo Bá Ṣàìgbọràn Sáwọn Òbí Mi?

Ohun tó ti ṣẹlẹ̀ ti ṣẹlẹ̀, àmọ́ o lè ṣe ohun tí kò ní jẹ́ kí ọ̀rò náà burú sí i. Àpilẹ̀kọ yìí máa sọ bó o ṣe lè ṣe é.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jẹ́ Káwọn Òbí Mi Fọkàn Tán Mi?

Ohun mẹ́ta tó o lè ṣe tá á jẹ́ kí wọ́n túbọ̀ fún ẹ lómìnira..

Ṣé Ó Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé Àwọn Òbí Rẹ Kò Fẹ́ Kó O Gbádùn Ara Rẹ Rárá?

Ṣé kí n yọ́ jáde lọ gbádùn ara mi, àbí kí n sòótọ́ fún àwọn òbí mi?

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Òbí Mi Bá Ń Ṣàìsàn?

Ìwọ nìkan kọ́ nirú ẹ̀ ti ṣẹlẹ̀ sí. Wo ohun tó ran àwọn méjì lọ́wọ́.

Ǹjẹ́ Àwọn Òbí Rẹ Fẹ́ Kọ Ara Wọn Sílẹ̀?

Báwo lo ṣe lè yẹra fún dídi ìbínú àti ìbànújẹ́ sọ́kàn?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Jẹ́ Kí Àlàáfíà Máa Wà Láàárín Èmi àti Àbúrò Tàbí Ẹ̀gbọ́n Mi?

O nífẹ̀ẹ́ wọn lóòótọ́, àmọ́ nígbà míì, wọ́n lè múnú bí ẹ gan-an.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Káwọn Òbí Mi Má Bàa Máa Tojú Bọ Ọ̀rọ̀ Mi Jù?

Ṣé ó ń ṣe ẹ́ bíi pé àwọn òbí ẹ ń tojú bọ ọ̀rọ̀ ẹ? Ṣé nǹkan wà tó o lè ṣe kó má bàa máa ṣe ẹ́ bẹ́ẹ̀?

Ṣé Mo Ti Tó Ẹni Tó Ń Kúrò Nílé?

Àwọn ìbéèrè wo ló yẹ kó o gbé yẹ̀ wò kó o tó ṣe irú ìpinnu pàtàkì yẹn?

Technology

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Àwọn Géèmù orí Kọ̀ǹpútà?

O lè má tíì ronú nípa àǹfààní tó lè ṣe ẹ́ àti àkóbá tó lè ṣe fún ẹ.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?

Ọ̀rọ tó o fi ránṣẹ́ lórí fóònù lè ba àjọṣe tó o ní pẹ̀lú àwọn míì jẹ́, ó sì lè bà ẹ́ lórúkọ̀ jẹ́. Kà bó ṣe lè ṣẹlẹ̀.

Ṣó Di Dandan Kéèyàn Púpọ̀ Mọ̀ Mí Lórí Ìkànnì Àjọlò?

Àwọn kan máa ń fẹ̀mí ara wọn wewu torí kí wọ́n lè lọ́rẹ̀ẹ́ tó pọ̀. Ṣó yẹ kéèyàn fẹ̀mí ara ẹ̀ wewu torí káwọn èèyàn lè gba tiẹ̀?

Àkóbá Wo Ni Ìkànnì Àjọlò Lè Ṣe fún Mi?

Lílo ìkànnì àjọlò lè di bárakú. Àwọn àbá yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó má bàa kó bá ẹ.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Gbígbé Fọ́tò Sórí Ìkànnì?

Tó o bá ń gbé fọ́tò ẹ sórí ìkànnì, àwọn ọ̀rẹ́ àtàwọn ẹbí ẹ lè rí i, á sì rọrùn láti máa kàn síra yín, àmọ́ ó tún léwu.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Mi Látorí Íńtánẹ́ẹ̀tì?

Ohun tó yẹ kó o mọ̀ àti ohun tó o lè ṣe láti dáàbò bo ara ẹ.

Ṣó Dáa Kéèyàn Máa Ṣe Ohun Tó Pọ̀ Lẹ́ẹ̀kan Náà?

Ṣé o lè ṣe nǹkan tó pọ̀ lẹ́ẹ̀kan náà kí ọkàn ẹ má sì pínyà?

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ́ Béèyàn Ṣe Ń Pọkàn Pọ̀?

Kíyè sí àwọn ipò mẹ́tà tó ti ṣeé ṣe kí ẹ̀rọ ìgbàlódé ṣàkóbá fún bó o ṣe ń pọkàn pọ̀ àti ohun tó o lè ṣe kó o lè túbọ̀ pọkàn pọ̀.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífi Ohun Tó Ń Mọ́kàn Fà sí Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?

Ṣé àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ò tíì máa fipá mú ẹ pé kó o fi ohun tó ń mọ́kàn fà sí ìṣekúṣe ránṣẹ́ sáwọn lórí fóònù? Kí ló lè tẹ̀yìn ẹ̀ yọ tó o bá ṣe bẹ́ẹ̀? Àbí o rò pé kò sóhun tó burú níbẹ̀, pé ẹ kàn ń tage lásán ni?

Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Táwọn Òbí Mi Bá Sọ Pé Kí N Má Lo Ìkànnì Àjọlò?

Ó dà bíi pé gbogbo èèyàn ló ń lo ìkànnì àjọlò, àmọ́ ṣe bẹ́ẹ̀ lọ̀rọ̀ rí? Kí lo lè ṣe táwọn òbí ẹ bá sọ pé kó o má lò ó?

Ilé Ẹ̀kọ́

Kí Ni Mo Lè Ṣe Kí Àárín Èmi àti Olùkọ́ Mi Lè Gún?

Tó o bá ní olùkọ́ tó dà bíi pé ó burú, o lè ṣe ohun tí ayé ò fi ní sú ẹ nílè ìwé. Gbìyànjú àwọn àbá tó wà nísàlẹ̀ yìí.

Ṣé Apá Mi Á Ká Àwọn Iṣẹ́ Àṣetiléwá Báyìí?

Tó bá jẹ́ pé kò rọrùn fún ẹ láti ṣe àwọn iṣẹ́ àṣetiléwá tí wọ́n ń fún ẹ, má ṣe rò pé òkè ìṣòrò tó ò lè borí ni.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Tí Mo Bá Ń Kàwé Látilé

Ọ̀pọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ ló ti ń kẹ́kọ̀ọ́ látilé wọn báyìí. Àwọn àbá márùn-ún tó lè ṣe ẹ́ láǹfààní nínú “kíláàsì” rẹ tuntun.

Ṣé O Kórìíra Iléèwé?

Ṣé olùkọ́ rẹ ń fi nǹkan sú ẹ? Ṣé ó jọ pé àwọn ẹ̀kọ́ kíláàsì kan ń fi àkókò rẹ ṣòfò ni?

Kí Nìdí Tí Mo Fi Ń Gba Òdo Nílé Ìwé?

Má jẹ́ kó sú ẹ, kíyè sí ohun mẹ́fà tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́.

Kí Nìdí Tó Fi Dáa Kéèyàn Kọ́ Èdè Míì?

Ìṣòro wo lo máa kojú? Àmọ́ èrè wo ló wà níbẹ̀?

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?​—Apá 1: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?

Ǹjẹ́ wàá fẹ́ mọ bó o ṣe lè túbọ̀ máa fi ìdánilójú ṣàlàyé ìdí tó o fi gbà gbọ́ pé Ọlọ́run wà fáwọn ẹlòmíì? Kà nípa àwọn ohun tó o lè fi fèsì tí ẹnì kan bá sọ pé ìgbàgbọ́ tó o ní pé Ọlọ́run wà kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀.

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?​—Apá 3: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?

Ṣé ó yẹ kó o di alátakò ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì kó o tó lè gbà pé Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo?

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?​—Apá 4: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìṣẹ̀dá?

Kò dìgbà tó o bá tó di ọ̀gá nídìí ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì kó o tó lè ṣàlàyé ìdí tó o fi rò pé ó bọ́gbọ́n mu ká gbà pẹ́ ẹnì kan ló dá gbogbo nǹkan tó wà láyé. Lo àlàyé tó bọ́gbọ́n mu tó wà nínú Bíbélì.

Life Skills

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Èrò Tí Kò Tọ́?

Tó o bá ń tẹ̀ lé àwọn àbá yìí wàá lè kọ́ béèyàn ṣe ń ronú lọ́nà tó tọ́.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàkóso Ìbínú Mi?

Àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ márùn-ún tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ṣàkóso ìbínú rẹ.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Borí Àníyàn?

Àwọn ohun mẹ́fà tó máa jẹ́ kí àníyàn ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí kò sì ní pa ẹ́ lára.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Fara Da Ẹ̀dùn Ọkàn Téèyàn Mi Bá Kú?

Ó lè gba àkókò díẹ̀ kí ẹ̀dùn ọkàn tá a ní tó lọ. Ronú nípa àwọn àbá tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí, kó o sì ṣiṣẹ́ lórí àwọn èyí tó bá ipò rẹ mu jù lọ.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Àjálù Bá Dé Bá Mi?

Àwọn ọ̀dọ́ kan sọ ohun tó ràn wọ́n lọ́wọ́.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ Ìdẹwò?

Wo ohun mẹ́ta tó o lè ṣe kó o lè borí àwọn èrò tí kò tọ́.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Àkókò Lò?

Ohun márùn-ún lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o má bàa máa fi àkókò ẹ tó ṣeyebíye ṣòfò.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Kò Fi Ní Máa Rẹ̀ Mí Jù?

Kí ló lè fà á tó fi máa rẹni gan-an? Ṣé ó máa ń rẹ̀ ẹ́ gan-an? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, kí lo lè ṣe nípa rẹ̀?

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Owó Ná?

Ṣe o ti lọ sílé ìtajà rí pé kó o lọ wo ohun tí wọ́n ń tà níbẹ̀, àmọ́ tó jẹ́ pé nígbà tó o fi máa jáde níbẹ̀, o ti ra ọjà tó wọ́n gan-an? Tó bá ti ṣe ẹ rí, àpilẹ̀kọ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Nípa Àwọn Àṣìṣe Mi?

Gbogbo èèyàn ló ń ṣàṣìṣe, àmọ́ gbogbo èèyàn kọ́ ló ń kẹ́kọ̀ọ́ nínú àṣìṣe.

Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Tí Wọ́n Bá Fún Mi Nímọ̀ràn?

Àwọn kan lè fọ́ yángá tí wọ́n bá fún wọn nímọ̀ràn, ṣe ni wọ́n dà bí àwo ẹlẹgẹ́ kan tó lè fọ́ nígbàkigbà. Ṣẹ́ irú ẹni bẹ́ẹ̀ ni ẹ́?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Jẹ́ Olóòótọ́?

Ṣé àwọn tí kì í ṣòótọ́ tiẹ̀ máa ń jìyà kankan?

Báwo Ni Mo Ṣe Ní Ìforítì Tó?

Torí pé kò lè ṣe kí ìṣòro má wà, ó ṣe pàtàkì pé kó o ní ìforítì, yálà ìṣòro tó ń bá ẹ fínra kére tàbí ó pọ̀.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ́ Béèyàn Ṣe Ń Pọkàn Pọ̀?

Kíyè sí àwọn ipò mẹ́tà tó ti ṣeé ṣe kí ẹ̀rọ ìgbàlódé ṣàkóbá fún bó o ṣe ń pọkàn pọ̀ àti ohun tó o lè ṣe kó o lè túbọ̀ pọkàn pọ̀.

Kí Nìdí Tó Fi Dáa Kéèyàn Kọ́ Èdè Míì?

Ìṣòro wo lo máa kojú? Àmọ́ èrè wo ló wà níbẹ̀?

Ṣé Mo Ti Tó Ẹni Tó Ń Kúrò Nílé?

Àwọn ìbéèrè wo ló yẹ kó o gbé yẹ̀ wò kó o tó ṣe irú ìpinnu pàtàkì yẹn?

Kí Ni Mo lè Ṣe Tí Mi Ò Fi Ní Máa Tijú Mọ́?

Máa wá bó o ṣe lè ní àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́, kó o lè mọ àwọn ohun tó ò mọ̀ tẹ́lẹ̀.

Kí Nìdí Táwọn Ẹgbẹ́ Mi Ò Fi Gba Tèmi?

Èwo ló dáa jù nínú káwọn tíwà wọn ò dáa gba tìẹ àti pé kó o jẹ́ káwọn èèyàn mọ irú ẹni tó o jẹ́ gan an?

Nje Iwa Omoluwabi Tie Se Pataki?

Se iwa atijo ni abi o si wulo lode oni?

Kí Ló Dé Tó Jẹ́ Ọ̀rọ̀ Tí Ò Dáa Ló Máa Ń Jáde Lẹ́nu Mi Ṣáá?

Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí wàá fi máa ronú kó o tó sọ̀rọ̀?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Tọrọ Àforíjì?

Wo ìdí mẹ́ta tó fi dáa kó o sọ pé ‘Máà bínú,’ tó o bá tiẹ̀ rò pé ọwọ́ ẹ kọ́ ni gbogbo ẹ̀bi wà.

Kí Ni Kí Ń Ṣe Tí Ọ̀rẹ́ Mi Bá Ṣe Nǹkan Tó Dùn Mí?

Arẹ́májà kan ò sí. Ṣùgbọ́n kí lo lè ṣe tí ọ̀rẹ́ rẹ bá ṣe ohun tó dùn ẹ́?

Irú Èèyàn Tó O Jẹ́

Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí O Máa Ṣe Bí Àwọn Tí Ò Ń Wò Nínú Fíìmù Tàbí Lórí Tẹlifíṣọ̀n?​—Apá 1: Fún Àwọn Ọ̀dọ́bìnrin

Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ tó ń ṣe bí àwọn èèyàn tó wà nínú fíìmù tàbí lórí tẹlifíṣọ̀n rò pé àwọn ń ṣe ohun tó dáa, wọn ò mọ̀ pé ìwà oníwà làwọn ń kọ́.

Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí O Máa Ṣe Bí Àwọn Tí Ò Ń Wò Nínú Fíìmù Tàbí Lórí Tẹlifíṣọ̀n?​—Apá 2: Fún Àwọn Ọkùnrin

Sé àwọn èèyàn á gba tìẹ tó o bá ń ṣe bíi ti àwọn tí ò ń rí nínú fíìmù tàbí nínú ìpolówó?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Jẹ́ Olóòótọ́?

Ṣé àwọn tí kì í ṣòótọ́ tiẹ̀ máa ń jìyà kankan?

Báwo Ni Mo Ṣe Ní Ìforítì Tó?

Torí pé kò lè ṣe kí ìṣòro má wà, ó ṣe pàtàkì pé kó o ní ìforítì, yálà ìṣòro tó ń bá ẹ fínra kére tàbí ó pọ̀.

Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Tí Wọ́n Bá Fún Mi Nímọ̀ràn?

Àwọn kan lè fọ́ yángá tí wọ́n bá fún wọn nímọ̀ràn, ṣe ni wọ́n dà bí àwo ẹlẹgẹ́ kan tó lè fọ́ nígbàkigbà. Ṣẹ́ irú ẹni bẹ́ẹ̀ ni ẹ́?

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Mi?

Ẹ̀rí ọkàn ẹ máa ń fi irú ẹni tó o jẹ́ àtohun tó o kà sí pàtàkì hàn. Kí ni ẹ̀rí ọkàn ẹ ń sọ nípa irú ẹni tó o jẹ́?

Ṣé Gbogbo Nǹkan Ni Mo Máa Ń Fẹ́ Ṣe Láìṣe Àṣìṣe Kankan?

Báwo lo ṣe lè fìyàtọ̀ sáàárín kó o máa ṣe gbogbo ohun tó o lè ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ẹ àti kó o máa lé ohun tí ọwọ́ ẹ̀ ò lè tẹ̀?

Ṣó Di Dandan Kéèyàn Púpọ̀ Mọ̀ Mí Lórí Ìkànnì Àjọlò?

Àwọn kan máa ń fẹ̀mí ara wọn wewu torí kí wọ́n lè lọ́rẹ̀ẹ́ tó pọ̀. Ṣó yẹ kéèyàn fẹ̀mí ara ẹ̀ wewu torí káwọn èèyàn lè gba tiẹ̀?

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Mo Bá Ń Hùwà Tí Ò Dáa Lábẹ́lẹ̀?

Ohun mẹ́rin tó o lè ṣe kó o lè jáwọ́ nínú ìwà yìí.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Rẹ́ni Tó Dáa Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe?

Tó o bá rí ẹni tó dáa tó o lè tẹ̀lé àpẹẹrẹ rẹ̀, ìyẹn máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti yẹra fún ìṣòro, ọwọ́ rẹ máa tẹ àwọn àfojúsùn rẹ, wà á sì ṣe àṣeyọrí. Àmọ́ àpẹẹrẹ tani kó o tẹ̀lé?

Kí Ni Mo Lè Ṣe Nípa Àwọn Àṣìṣe Mi?

Gbogbo èèyàn ló ń ṣàṣìṣe, àmọ́ gbogbo èèyàn kọ́ ló ń kẹ́kọ̀ọ́ nínú àṣìṣe.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ Ìdẹwò?

Wo ohun mẹ́ta tó o lè ṣe kó o lè borí àwọn èrò tí kò tọ́.

Báwo Ni Ìmúra Mi Ṣe Rí?

Kọ́ bí o ṣe lè yẹra fún àwọn àṣìṣe mẹ́ta tí àwọn èèyàn máa ń ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìmúra.

Ṣé Ó Yẹ Kí N Fín Ara?

Báwo lo ṣe lè ṣèpinnu tó bọ́gbọ́n mu?

Bad Habits

Ṣé Ó Fi Bẹ́ẹ̀ Burú Kéèyàn Máa Ṣépè?

Kéèyàn máa ṣépè kì í ṣe ohun tuntun, àmọ́ ṣé ó burú?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Yẹra fún Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe?

Kí ló jọra nínú wíwo àwòrán ìṣekúṣe àti mímu sìgá?

Ṣé Wíwo Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Èèyàn Fà sí Ìṣekúṣe Ti Mọ́ Ẹ Lára?

Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀ pé ohun tó ń mú ọkàn èèyàn fà sí ìṣekúṣe kò dára.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ Ìdẹwò?

Wo ohun mẹ́ta tó o lè ṣe kó o lè borí àwọn èrò tí kò tọ́.

Ṣó Dáa Kéèyàn Máa Ṣe Ohun Tó Pọ̀ Lẹ́ẹ̀kan Náà?

Ṣé o lè ṣe nǹkan tó pọ̀ lẹ́ẹ̀kan náà kí ọkàn ẹ má sì pínyà?

Free Time

Ṣé Mo Lè Yan Orin Tó Bá Ṣáà Ti Wù Mí?

Torí pé ipa tó lágbára ni orin máa ń ní lórí wa, kọ́ nípa bí o ṣe lè fi ọgbọ́n yan irú orin tí wàá máa gbọ́.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Àwọn Géèmù orí Kọ̀ǹpútà?

O lè má tíì ronú nípa àǹfààní tó lè ṣe ẹ́ àti àkóbá tó lè ṣe fún ẹ.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Eré Ìdárayá?

Ṣàyẹ̀wò irú eré tó ò ń ṣe, bó o ṣe ń ṣe é àti bí àkókò tó o fi ń ṣe eré ọ̀hún bá ṣe pọ̀ tó.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Àkókò Lò?

Ohun márùn-ún lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o má bàa máa fi àkókò ẹ tó ṣeyebíye ṣòfò.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Nǹkan Bá Tojú Sú Mi?

Ṣé ẹ̀rọ ìgbàlódé ló wá kàn? Ṣé ojú tó o bá fi wo ọ̀rọ̀ náà lè mú kí nǹkan yí pa dà?

Ṣé Ẹgbẹ́ Òkùnkùn Ò Léwu?

Ọ̀pọ̀ ló nífẹ̀ẹ́ sí wíwo ìràwọ̀, bíbá ẹ̀mí lò, àwọn àǹjọ̀ọ̀nú, iṣẹ́ oṣó àti àjẹ́. Ṣé àwọn ewu kan wà tó yẹ kó o mọ̀?

Ṣé Ó Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé Àwọn Òbí Rẹ Kò Fẹ́ Kó O Gbádùn Ara Rẹ Rárá?

Ṣé kí n yọ́ jáde lọ gbádùn ara mi, àbí kí n sòótọ́ fún àwọn òbí mi?

Ìbálòpọ̀

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Wọ́n Bá Ń Fi Ìṣekúṣe Lọ̀ Mí?

Kà nípa bí wọ́n ṣe máa ń fi ìṣekúṣe lọni àti ohun tó o lè ṣe tí wọ́n bá ń fi ìṣekúṣe lọ̀ ẹ́.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìfipá Báni Ṣèṣekúṣe?​—Apá 1: Bó O Ṣe Lè Yẹra Fún un

Àwọn àbá mẹ́ta tó lè ràn ọ́ lọ́wọ́ kí o lè dáàbò ara rẹ lọ́wọ́ àwọn tó ń fipá báni ṣèṣekúṣe.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìfipá Báni Ṣèṣekúṣe?​—Apá 2: Bó O Ṣe Lè Kọ́fẹ Pa Dà

Ka nípa ohun tí àwọn tí wọ́n fipá bá ṣèṣekúṣe àmọ́ tí wọ́n ti kọ́fẹ pa dà sọ.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìbálòpọ̀?

Tí wọ́n bá bi ẹ́ pé, ‘Ṣó o ti ní ìbálòpọ̀ rí?’ ṣé o lè fi Bíbélì ṣàlàyé ohun tó o gbà gbọ́ nípa ìbálòpọ̀?

Ṣé A Lè Ka Fífi Ẹnu Lá Ẹ̀yà Ìbímọ Ẹlòmíì sí Ìbálòpọ̀?

Ṣé ọmọbìnrin kan lè lóyún tó bá ń fi ẹnu lá ẹ̀yà ìbímọ ẹlòmíì?

Ṣó Burú Kí Ọkùnrin Máa Fẹ́ Ọkùnrin àbí Kí Obìnrin Máa Fẹ́ Obìnrin?

Ṣé Bíbélì fi kọ́ni pé èèyàn burúkú ni àwọn ọkùnrin tó ń fẹ́ ọkùnrin àti àwọn obìnrin tó ń fẹ́ obìnrin? Ṣé Kristẹni kan lè máa ṣe ohun tó máa múnú Ọlọ́run dùn tí ọkàn ẹ̀ bá tiẹ̀ ń fà sí àwọn tó jẹ́ ọkùnrin bíi tiẹ̀?

Ṣé Ọkàn Rẹ Ń Fà sí Ẹ̀yà Kan Náà, àbí Ó Túmọ̀ Sí Pé Abẹ́yà-Kan-Náà-Lòpọ̀ Ni Ẹ́

Ṣé ó burú kí ọkàn ẹni máa fà sí ẹ̀yà kan náà? Kí ló yẹ kó o ṣe?

Báwo Lo Ò Ṣe Ní Jẹ́ Káwọn Ojúgbà Rẹ Mú Ẹ Ṣèṣekúṣe?

Ka díẹ̀ lára irọ́ àti òótọ́ nípa ìbálòpọ̀. Àpilẹ̀kọ yìí lè mú kó o ṣe àwọn ìpinnu tó dáa.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbọ́kàn Kúrò Lórí Ìbálòpọ̀?

Kí lo lè ṣe tí èrò nípa ìbálòpọ̀ bá wá sí ẹ lọ́kàn?

Ṣé Mo Lè Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Má Ṣe Ní Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó?

Ṣé ẹ̀jẹ́ yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti yẹra fún ìbálòpọ̀ ṣáájú ìgbéyàwó?

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífi Ohun Tó Ń Mọ́kàn Fà sí Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?

Ṣé àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ò tíì máa fipá mú ẹ pé kó o fi ohun tó ń mọ́kàn fà sí ìṣekúṣe ránṣẹ́ sáwọn lórí fóònù? Kí ló lè tẹ̀yìn ẹ̀ yọ tó o bá ṣe bẹ́ẹ̀? Àbí o rò pé kò sóhun tó burú níbẹ̀, pé ẹ kàn ń tage lásán ni?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Yẹra fún Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe?

Kí ló jọra nínú wíwo àwòrán ìṣekúṣe àti mímu sìgá?

Ṣé Wíwo Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Èèyàn Fà sí Ìṣekúṣe Ti Mọ́ Ẹ Lára?

Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀ pé ohun tó ń mú ọkàn èèyàn fà sí ìṣekúṣe kò dára.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ Ìdẹwò?

Wo ohun mẹ́ta tó o lè ṣe kó o lè borí àwọn èrò tí kò tọ́.

Fífẹ́ra Sọ́nà

Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?

Ohun márùn-ún tó máa jẹ́ kó o mọ̀ bóyá o ti ṣe tán láti lẹ́ni tí wàá máa fẹ́, tó o sì lè bá ṣègbéyàwó.

Ṣé Ó Burú Kéèyàn Máa Tage?

Kí ló túmọ̀ sí gan-an kéèyàn máa tage? Kí ló máa ń mú káwọn kan ṣe bẹ́ẹ̀? Ṣé ó tiẹ̀ léwu?

Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán Ni Wá àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́?—Apá 1: Báwo Ni Ẹni Yìí Ṣe Ń Ṣe sí Mi?

Wo àwọn ohun tó o lè ṣe kó o lè mọ̀ bóyá bí ẹnì kan ṣe ń ṣe sí ẹ fi hàn pé ó fẹ́ kẹ́ ẹ máa fẹ́ra àbí ó kàn fẹ́ kẹ́ ẹ jẹ́ ọ̀rẹ́.

Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán Ni Wá àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́?—Apá 2: Báwo Ní Mo Ṣe Ń Ṣe sí Ẹni Yìí?

Ṣé kì í ṣe pé ọ̀rẹ́ rẹ ti ń wò ó pé o fẹ́ kí ẹ máa fẹ́ra? Wo àwọn àbá yìí.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ̀dùn Ọkàn Tá Ò Bá Fẹ́ra Wa Mọ́?

Wo bó o ṣe lè bọ́ lọ́wọ́ ẹ̀dùn ọkàn tó lágbára.

Physical Health

Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Ní Àìsàn Tó Ò Ń Bá Fínra? (Apá 1)

Àwọn ọ̀dọ́ mẹ́rin sọ ohun tó ń jẹ́ kí wọ́n lè máa fara da àìsàn tó ń ṣe wọ́n, kínú wọn sì máa dùn.

Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Ní Àìsàn Tó Ò Ń Bá Fínra? (Apá 2)

Ka ìrírí táwọn ọ̀dọ́ kan tó ń ṣàìsàn tó le fẹnu ara wọn sọ nípa bí wọ́n ṣe ń fayọ̀ fara da ohun tó ń ṣe wọ́n.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Mo Bá Ní Àìsàn tí Mò Ń Bá Fínra? (Apá 3)

Ohun táwọn ọ̀dọ́ mẹ́ta sọ lè jẹ́ kó o mọ bí wàá ṣe máa fara dà á.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Ìbàlágà?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó ṣe máa rí àti bó o ṣe lè kojú ẹ̀, kó o sì ṣàṣeyọrí.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Kò Fi Ní Máa Rẹ̀ Mí Jù?

Kí ló lè fà á tó fi máa rẹni gan-an? Ṣé ó máa ń rẹ̀ ẹ́ gan-an? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, kí lo lè ṣe nípa rẹ̀?

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ọtí?

Mọ ohun tó o lè ṣe kí ọwọ́ òfin má bàa tẹ̀ ẹ́, kí orúkọ ẹ má bà jẹ́ tàbí kí wọ́n má bàa fipá bá ẹ lò pọ̀, kí ọtí má sì di bárakú fún ẹ tàbí kó o fẹ̀mí ara ẹ ṣòfò.

Ohun Tó Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Sìgá Mímu?

Tó o bá ronú lórí ewu tó wà nínú mímu sìgá, wàá rí i pé ohun tó lè pa wọ́n lára làwọn ojúgbà ẹ àtàwọn gbajúgbajà fi ń ṣayọ̀. Mọ àwọn ewu tó wà níbẹ̀ àti bó o ṣe lè yẹra fún un.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Kí N Lè Máa Sùn Dáadáa?

Ohun méje táá jẹ́ kó o túbọ̀ máa sùn dáadáa.

Báwo Ni Eré Ìmárale Ṣe Lè Máa Wù Mí Ṣe?

Yàtọ̀ sí ìlera tó dá ṣáṣá, ǹjẹ́ àǹfààní míì wà nínú kéèyàn máa ṣeré ìmárale déédéé?

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Jẹ Oúnjẹ Tó Ṣara Lóore?

Àwọn tí oúnjẹ tí kò ṣara lóore bá mọ́ lára nígbà tí wọ́n wà lọ́dọ̀ọ́ máa ń bá a lọ títí wọ́n á fi dàgbà.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dín Bí Mo Ṣe Sanra Kù?

Má ṣe rò pé oúnjẹ àrà ọ̀tọ̀ kan ló máa dín bó o ṣe sanra kù, kàkà bẹ́ẹ̀, kọ́ ọ̀nà ìgbésí ayé tó yàtọ̀.

Emotional Health

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Èrò Tí Kò Tọ́?

Tó o bá ń tẹ̀ lé àwọn àbá yìí wàá lè kọ́ béèyàn ṣe ń ronú lọ́nà tó tọ́.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Mo Bá Ń Sorí Kọ́?

Àwọn àbá yìí máa jẹ́ kó o mọ ohun tó yẹ kó o ṣe kó o lè bọ́ nínú ẹ̀.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Borí Àníyàn?

Àwọn ohun mẹ́fà tó máa jẹ́ kí àníyàn ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí kò sì ní pa ẹ́ lára.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàkóso Ìbínú Mi?

Àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ márùn-ún tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ṣàkóso ìbínú rẹ.

Ṣé Gbogbo Nǹkan Ni Mo Máa Ń Fẹ́ Ṣe Láìṣe Àṣìṣe Kankan?

Báwo lo ṣe lè fìyàtọ̀ sáàárín kó o máa ṣe gbogbo ohun tó o lè ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ẹ àti kó o máa lé ohun tí ọwọ́ ẹ̀ ò lè tẹ̀?

Báwo Ni Mo Ṣe Ní Ìforítì Tó?

Torí pé kò lè ṣe kí ìṣòro má wà, ó ṣe pàtàkì pé kó o ní ìforítì, yálà ìṣòro tó ń bá ẹ fínra kére tàbí ó pọ̀.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Fara Da Ẹ̀dùn Ọkàn Téèyàn Mi Bá Kú?

Ó lè gba àkókò díẹ̀ kí ẹ̀dùn ọkàn tá a ní tó lọ. Ronú nípa àwọn àbá tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí, kó o sì ṣiṣẹ́ lórí àwọn èyí tó bá ipò rẹ mu jù lọ.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Àjálù Bá Dé Bá Mi?

Àwọn ọ̀dọ́ kan sọ ohun tó ràn wọ́n lọ́wọ́.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Ayé Bá Sú Mi?

Àwọn nǹkan mẹ́rin tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tó bá ń ṣe ẹ́ bíi pé kó o pa ara ẹ.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Mi Látorí Íńtánẹ́ẹ̀tì?

Ohun tó yẹ kó o mọ̀ àti ohun tó o lè ṣe láti dáàbò bo ara ẹ.

Àkóbá Wo Ni Ìkànnì Àjọlò Lè Ṣe fún Mi?

Lílo ìkànnì àjọlò lè di bárakú. Àwọn àbá yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó má bàa kó bá ẹ.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Ìbàlágà?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó ṣe máa rí àti bó o ṣe lè kojú ẹ̀, kó o sì ṣàṣeyọrí.

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Kò Fi Ní Máa Rẹ̀ Mí Jù?

Kí ló lè fà á tó fi máa rẹni gan-an? Ṣé ó máa ń rẹ̀ ẹ́ gan-an? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, kí lo lè ṣe nípa rẹ̀?

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìfipá Báni Ṣèṣekúṣe?​—Apá 2: Bó O Ṣe Lè Kọ́fẹ Pa Dà

Ka nípa ohun tí àwọn tí wọ́n fipá bá ṣèṣekúṣe àmọ́ tí wọ́n ti kọ́fẹ pa dà sọ.

Fífọ̣kànsin Ọlọ́run

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?​—Apá 1: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?

Ǹjẹ́ wàá fẹ́ mọ bó o ṣe lè túbọ̀ máa fi ìdánilójú ṣàlàyé ìdí tó o fi gbà gbọ́ pé Ọlọ́run wà fáwọn ẹlòmíì? Kà nípa àwọn ohun tó o lè fi fèsì tí ẹnì kan bá sọ pé ìgbàgbọ́ tó o ní pé Ọlọ́run wà kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀.

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?​—Apá 3: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?

Ṣé ó yẹ kó o di alátakò ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì kó o tó lè gbà pé Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo?

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?​—Apá 4: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìṣẹ̀dá?

Kò dìgbà tó o bá tó di ọ̀gá nídìí ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì kó o tó lè ṣàlàyé ìdí tó o fi rò pé ó bọ́gbọ́n mu ká gbà pẹ́ ẹnì kan ló dá gbogbo nǹkan tó wà láyé. Lo àlàyé tó bọ́gbọ́n mu tó wà nínú Bíbélì.

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Gbàdúrà?

Ṣé torí kí ara kàn lè tuni léèyàn ṣe máa ń gbàdúrà ni, àbí ó kọjá ìyẹn?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Lọ sí Gbọ̀ngàn Ìjọba?

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń pàdé ní ẹ̀ẹ̀mejì lọ́sẹ̀ ní ilé ìjọsìn tí wọ́n máa ń pè ní Gbọ̀ngàn Ìjọba. Kí ni wọ́n ń ṣe níbẹ̀, àǹfààní wo lo sì máa rí tó o bá lọ síbẹ̀?

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Mo Bá Ń Hùwà Tí Ò Dáa Lábẹ́lẹ̀?

Ohun mẹ́rin tó o lè ṣe kó o lè jáwọ́ nínú ìwà yìí.

Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?​—Apá Kìíní: Wo Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì

Tó bá ṣẹlẹ̀ pé o rí àpótí ìṣura ńlá kan, ó dájú pé ó máa wù ẹ́ láti mọ nǹkan tó wà nínú ẹ̀? Bíbélì ò yàtọ̀ sí àpótí ìṣura. Àwọn ìṣura ọgbọ́n tó pọ̀ gan-an tó sì wúlò ló wà nínú ẹ̀.

Báwo ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?​—Apá Kejì: Jẹ́ Kí Bíbélì Gbádùn Mọ́ Ẹ

Ohun márun-un tó máa jé kó o rí ara ẹ nínú Bíbélì kíkà rẹ.

Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá 3: Túbọ̀ Jàǹfààní Púpọ̀ Bó o Ṣe Ń Ka Bíbélì

Ohun mẹ́rin tó o lè ṣe kó o lè túbọ̀ jàǹfààní púpọ̀ bó o ṣe ń ka Bíbélì.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Mi?

Ẹ̀rí ọkàn ẹ máa ń fi irú ẹni tó o jẹ́ àtohun tó o kà sí pàtàkì hàn. Kí ni ẹ̀rí ọkàn ẹ ń sọ nípa irú ẹni tó o jẹ́?

Ṣé Kí N Ṣèrìbọmi?: Ohun Tí Ìrìbọmi Túmọ̀ Sí

Kó o tó ṣèrìbọmi, ó yẹ kó o kọ́kọ́ mọ ohun tó túmọ̀ sí.

Ṣé Kí N Ṣèrìbọmi?​—Bó O Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrìbọmi

Ronú lórí àwọn ìbéèrè yìí kó o lè mọ̀ bóyá ó ti ṣe tán láti ṣèrìbọmi.

Ṣé Kí N Ṣèrìbọmi?​—Kí Ló Ń Dá Mi Dúró?

Tí ẹ̀rù bá ń bà ẹ́ láti ṣèrìbọmi, àpilẹ̀kọ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìbẹ̀rù náà.

Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Lẹ́yìn Tí Mo Bá Ṣèrìbọmi?—Apá 1: Máa Ṣe Àwọn Ohun Táá Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run

Lẹ́yìn tó o bá ṣèrìbọmi, ó gbọ́dọ̀ sapá láti mú kú àjọṣe rẹ pẹ̀lú Ọlọ́run sunwọ̀n sí i. Máa ka Bíbélì, máa gbàdúrà, máa sọ ohun tó o gbà gbọ́ fáwọn míì, kó o sì máa lọ sípàdé déédéé.

Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Lẹ́yìn Tí Mo Bá Ṣèrìbọmi?​​—Apá 2: Máa Ṣe Ohun Tó Tọ́ Lójú Ọlọ́run

Wàá rí bó o ṣe lè mú ìlérí tó ṣe nígbà tó ya ara ẹ sí mímọ́ ṣẹ.

Older Articles

Àpilẹ̀kọ “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé” Nínú Ìwé Ìròyìn Jí!

Ka ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ tí àkòrí ẹ̀ jẹ́ “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé” látọdún 1982 sí 2012.

Ṣé Ká Fira Wa Sílẹ̀? (Apá 1)

Téèyàn bá ti bá ẹnì kan ṣègbéyàwó, ó ti gbé tiẹ̀ nìyẹn. Torí náà, tó o bá ti ń da ọ̀rọ̀ ẹni tó ò ń fẹ́ rò, má kàn gbójú fo ohun tó ò ń rò o!

Ṣé Ká Fira Wa Sílẹ̀? (Apá 2)

Kì í ṣe ohun tó rọrùn rárá kéèyàn sọ pé òun máa fi ẹni tóun ń fẹ́ sílẹ̀. Ọ̀nà wo ló dáa jù téèyàn lè gbà ṣe é?